Home Gospel Music Laolu Gbenjo – EverGreen Yoruba Medley

Laolu Gbenjo – EverGreen Yoruba Medley

Download “EverGreen Yoruba Medley” SONG By

Laolu Gbenjo - EverGreen Yoruba Medley

Nigerian Christian/Gospel Artiste Released a New Single Titled “EverGreen Yoruba Medley”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What Do You Think About This Audio?

We Want To Hear From You All

Kindly Drop Your Comments

Watch Video (Mp4) Below:

EverGreen Yoruba Medley Lyrics By Laolu Gbenjo
Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán o
Ọba mímọ l'ọ'ba t'emi n sin
Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán o
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Lẹ'yìn Jésù kò má sẹ' ni kán o
Ọba mímọ l'ọ'ba t'emi n sìn nígbà gbogbo lojojumọ'
Lẹ'yìn Jésù ko má sẹ' ni kán o
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Lẹ'yìn Jésù ni mímọ
Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán ó (Ọba mímọ má ni)
Ọba mímọ l'ọ'ba tí mo n sìn (Lẹ'yìn Jésù)
Lẹ'yìn Jésù ko sẹ' ni kán ó (Alágbára gíga ní o)
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Jésù olùtọ́jú ènìyàn
Alágbára gíga-gíga gíga-gíga
Lọrun àti láyé bàbà mi mímọ o
Òdì kan gbé rẹ ni ja
Ọlọ'wọ'gbọgbọrọ tí ń yọ mọ rẹ lofin ayé
Àárín má tọ'ka lẹ'yìn
Ogberin lẹ'yìn aṣo' dodo bàbá Mímọ'
Sárà rẹ náà re
Baba olùtọ́jú ènìyàn
Sárà rẹ náà re
Olùtọ́jú mi nígbà gbogbo ẹ ṣé o
Jésù olùtọ́jú ènìyàn (Sárà rẹ ó ooo)
Sárà rẹ náà rẹ (Atobajaiye Elédùmarè bàbà mimọ)
Baba olùtọ́jú ènìyàn (Eh Sárà rẹ)
Sárà rẹ náà re
Èmi o màmà rí ọ rí o
Ọlọ'run mi
Ṣùgbọ'n mo rí ‘ṣẹ rẹ nínú ayé mi
Èmi o màmà rí ọ rí o
Ẹlẹ́dàá mi
Ṣùgbọ'n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi bàbà o Eh!
I have assurance Ọlọ́run mi bàbà mímọ
Wípé ẹ wa
I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa
Èmi o rí ọ rí o Ọlọ'run mi
Ṣùgbọ'n mo rí ‘ṣẹ rẹ (Ṣùgbọ́n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi mo rí' ọwọ rẹ bàbà mímọ)
Èmi o rí ọ rí o Ọlọ'run mi
Ṣùgbọ'n mo rí ‘ṣẹ rẹ
La la la la la la la la Olúwa o
I have assurance Ọlọ́run mi
Wípé ẹ wa
I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa
Ọlọ'run mi
Ọlọ'run mi
Ìwọ lójú tí mo fí ń ríran
Ìwọ ni kọ'kọ'rọ' tí mo fi ń ṣílẹ̀kùn
Ìwọ l ‘orin tí mo ń kọ eh
Ina ayé ẹ ò jẹ' kó jo mi
Kí ni mo ní ti mo lè fún ọ o
Mo wólẹ' mo ki ọ ó bàbà
Ọlọ'run mi
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe' yanu rẹ lórí mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Àní Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe' yanu rẹ lórí mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga pupọ
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe' yanu rẹ láyé mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe' yanu rẹ láyé mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà ooo
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà
(O f'aye mi dà bí rà dá bí rà)
(O f'aye mi dà bí rà dá bí rà)
(Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi)
(Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi)
Edumare f'ayé mi dá bí rà sẹ o
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà o
Lójú ọ'tá mi o gbé mi lékè
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà
Lójú ẹlẹ'tan ó wá s'ẹkún mi d'ẹ'rín ṣẹ oo
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà
Ó ra mi padà ó wà sọ mé d ‘ọmọ rẹ Eledumare Ẹ ṣé o
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà
Lójú ọ'tá mi o gbé mi lékè
Bàbá ń f'aye mi dá bí rà

Other Songs From For Laolu Gbenjo Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here