Home Gospel Music Sola Allyson – Eji Owuro

Sola Allyson – Eji Owuro

Download “Eji Owuro” SONG By

Sola Allyson - Eji Owuro

Nigerian Christian/Gospel Artiste Sola Allyson Released a New Single Titled “Eji Owuro”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What Do You Think About This Audio?

We Want To Hear From You All

Kindly Drop Your Comments

Watch Video (Mp4) Below:

Eji Owuro Lyrics By Sola Allyson
Duro timi o, Ololufe
ti ko labuku ni ko ba mi lo
Duro timi o, Ololufe
ti ko labawon ni ko ba mi lo
bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan
bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan
Femi bi oju ti n f'emu
Femi bi irun ti n f'ori
Femi bi eyin ti n f'enu
Femi teerin teerin
Femi taayo taayo
Femi taara taara
Ololufe feran mi laisetan
Femi bi oju ti n f'emu
Femi bi irun ti n f'ori
Femi bi eyin ti n f'enu
Femi teerin teerin
Femi taayo taayo
Femi taara taara
bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan
Ba mi s'ootito, Mo fe o tooto
Ba mi s'ododo, Mo fe o pelu ododo
Ba mi s'ootito, (Ololufe) Mo fe o tooto
Ba mi s'ododo, Mo fe o pelu ododo
B'ogiri o ba la'nu, Alangba o le w'ogiri
B'ogiri o ba la'nu, Alangba o le w'ogiri
Eleda lo yan wa papo, Esu ko ni yawa o
Ife bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
Ife to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan.
A ma lowo lowo
A ma kole mole
A ma bimo lemo
A ma sayo
A ma shola mola
Ka sa mufe Eledumare se, laisetan.
A ma lowo lowo
A ma kole mole
A ma bimo lemo
A ma sayo
A ma shola mola
Ka sa mufe Eledumare se, laisetan.
Ife bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
Ife to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan.
Gb'amoran mi, Ololufemi!
Oluranlowo la fi mi se fun o lat'orun wa
F'eti s'amoran mi, Ololufemi!
Oluranlowo la fi mi se fun o lat'orun wa
Kaj'orin ka s'ogo, l'oruko Olorun
Alabinrin la fi mi se fun o lat'orun wa
M'okan ku ro ni asan aye
Etan o da n kankan fun ni
Ife at'ope lo le mu wa l'aye ja lai labawon
M'okan ku ro ni asan aye
Etan o da n kankan fun ni
Ife at'ope lo le mu wa l'aye ja lai labawon
Ife bi Eji Owuro,
Latagbala Eledumare lo ti se wa
Ife to tooro minimini,
Tabawon aye kan o le ba je o
Ololufe feran mi laisetan.
Duro timi o, Ololufe
Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo
Duro timi o, Ololufe
Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo
Duro timi o, Ololufe
Ife ti ko leetan rara ni ko ba mi lo…

Other Songs From For Sola Allyson Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here