Home Gospel Music Sola Allyson – Oro Oluwa

Sola Allyson – Oro Oluwa

Free Download “Oro Oluwa” SONG By

Sola Allyson – Oro Oluwa

Nigerian Christian/Gospel Artiste Released a New Single Titled “Oro Oluwa”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.

Available Now at all Major Digital Music Streaming providers & Gospelmetrics. Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What do you think about this Audio?

We want to hear from you all

Drop your comments

Watch Video Mp4 Below:

Oro Oluwa (Lyrics) –
Ọrọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' Olúwa kòní lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Òun mo rí yẹ kó ba mí lẹ'ru
Òun mo rí yẹ kó mì mí lọ'kàn
Oti lẹ' yẹ kó fò mí láyà
Ṣùgbọ'n mo pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ mo pinnu láti mọ kan ro t'ori mo mọ pé Ọ'rọ' Olúwa, kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Kò ní lọ láì ṣẹ'
Kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìgbàgbọ' rẹ lo ń béèrè
Ìlérí a má ṣẹ'
Hmmmmm…
Ìbànújẹ' lè wá síbẹ' ọ'rọ' rẹ á ṣẹ'
Ìkorò lè pọ' o ṣùgb ‘adun la ja si
Mo gbójú mí ṣá pá òkè
Iranwọ' mí n bẹ láti ọ'dọ' Ọlọ'run òdòdó
Ìdánilójú yí mú ‘retí wá t'ori mó mọ pé
Ọ'rọ' rẹ sì mí (hmmm) kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' rẹ' sí mí réré ni kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ'
Ọlọ'run kìí ṣ' ènìyàn tó máa ṣe ké
Oti wí bẹ' àṣẹ bẹ dandan lo jẹ'
Bó tilẹ' wù kó rí ọ'rọ' rẹ àṣẹ
Olè pẹ' díẹ' ṣùgbọ́n pé kò yẹ (hmmm) rárá rárá
Òfìfo á dọ” pọ ìrora á di' rọrùn ká ní ‘retí
Adùn aapọ' aapẹ'
A fi rí gidi a fẹ'rẹ'ẹ' gẹ'dẹ' àpẹẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi sẹ ìlérí àṣẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi sẹ ìlérí a má ṣẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi ṣẹ ìlérí àṣẹ

Òun órí lè má ba ọ' lẹ'ru
Òun órí lè má mi ọ lọ'kàn
Oti lẹ' yẹ kó fò ọ láyà
Ṣùgbọ'n ko pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ pinnu láti mọ kan ro t'ori àjọ mọ ní pé
Ọ'rọ' rẹ sì wá réré ní (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Ìfẹ' Olúwa sì wá réré ni (Kó ni lọ láì ṣẹ')
O kan jọ búburú ni koni burú fún ọ ọmọ ènìyàn ọ'rọ' rẹ kii yẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Mójú kúrò nínú Júù Júù tó yọ ká gbójú rẹ sókè iranwo àwa (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Òun ni lọ'wọ' lọ'wọ' iranlọwọ nígbà tó wà àti ‘gbá tí ó wà ọ'rọ' rẹ kò ní lọ láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Gba lolu gbá lolu tọ gbá l' olùkọ' at' olùdarí ọ'rọ' rẹ réré ni (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Ọ'rọ' Olúwa (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Níwọ'n ìgbà tí mo gbẹ' kẹ'l ‘olú èmi ó ní rí' tijú kan lai lai lai (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Mo gbà lólu ‘rán lọ'wọ' mi ò mọ l' àrán mi lọ'wọ' ọ'rọ' rẹ kò ní láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Oti wí bẹ'ẹ' àṣẹ bẹ'ẹ' fún mi mo dúró mo dúró (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Eh! Eh! Ọ'rọ' Olúwa o (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Koni lọ láì ṣẹ' kò ní lọ láì ṣẹ' gbà bẹ gba bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Eh! Eh! Ọ'rọ' rẹ siwa ó rere ní (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Tújú rẹ ká tújú rẹ ká ọ'rọ' rẹ kò ní lọ láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Lábẹ' bó tilẹ' wù kori ọ'rọ' rẹ kọ'ni lọ láìṣe gbà bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Hmm… Ọ'rọ' Olúwa ó (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Other Tracks From Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here