Home Gospel Music Tope Alabi – Mimo L’oluwa

Tope Alabi – Mimo L’oluwa

Download “Mimo L'oluwa” SONG By

Tope Alabi Mimo L'oluwa

Nigerian Christian/Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “Mimo L'oluwa”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What Do You Think About This Audio?

We Want To Hear From You All

Kindly Drop Your Comments

Watch Video (Mp4) Below:

Mimo L'oluwa Lyrics By Tope Alabi
Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Egbageje irawo
Mimo
Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Agbagba merinlelogun
Lorigun mererin aye o
Mimo
Atoke atile
Mimo
Se ni won nke tantan o
Mimo
Ta ni yo gori Oke oluwa
Mimo
Tabi tani yo duro nine
Mimo
Eni to ni owo Mimo, ati aya funfun
Mimo o loluwa
Mimo o Mimo o Mimo o
Mimo o fun fun nene ni
Mimo
Kabiyesi eledumare Mimo
NLA
Gbogbo aye e teriba fun adari hurun
to ni emi inu eniyan pata
Onikokoro aye lowo
Adagagodo emi gbogbo eniyan
Olukangun orun, ajosun edumare
Jigbinigbin, awuwo bi ate ileke
Mimo
Opa tirin kanle o kan orun
Ajosun edumare, minimini ojo to njara o deyan
Mimo
Orun wawa nigba to padabo sipo
Olorun to sosupa dale torutoru
toun Soun gbogbo lasiko lasiko
to let feyin eni ti, ta le feyin re ti laelae
Are NLA, Oga tenikan o bi
To bimo Kari aye porogodo
Olowori gbogbo aye, orogodigo baba awon eru
Mimo Mimo
Oniwa funfun, adake se in,
Tenikan o le se un si
Ninu ogo gangan lo ti fohun
Ologo to ju Ogo lo ni
Mimo.
Kabiyo o si, emi o je fi osere, afi eni to be fegba query lido re.
Mi o je foju di o
ti o se wo loju wo
O ti e leti, ai le dibaje ni o
Baba NLA Ku Baba mi
O le pin yikin
Mimo
Gbogbo eni to be mi riri Oluwa, e Teri ba
Ewa riri fun tite re ki si
Ibere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikiji
Mimo
Tabubu, tale bu tan, pupo si ni gbogbo ojo
Eje ka sale fun rere ta ba mo riri
Emi inu awon woli
Atobitan, alainiye, popo koja riri
Terere koja kika, gungun lailopin
Ailetuwo, adaun ro, adaun se, adaun so
Oluwa inu awon orun, Oke NLA, arogunmatidi
Arabaribiti, aribirabata
Ejinkota biko yingirin
Ojo foke bi koyegere
Oke o le SA, Oke o le he
Koseni to le no aditu re, Olodumare
Iwo Lodi Iwo lo le tu, Oba NLA gbogbo agbaye loun
Teriba fun o baba Agba
Gbangba gbangba, jaranjaran, fenfefenfe
Iba o iba
Iwọ lodi Iwọ lo lè tu,
Ọba nla gbogbo àgbáyé lòún tẹriba fún ọ baba Agba
Gbángba gbángba, jaranjaran, fenfefenfe
Iba o iba…
Mímọ L'oluwa
Mímọ
Angẹli wọn mi ke
Mímọ
Àwọn Ọrùn wọn mi ke
Mímọ
Egbaagbeje ìràwọMímọ

Other Songs From Sinach Tope Alabi Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here