Download “Ilekun” SONG By sola allyson
Nigerian Christian/Gospel Artiste Sola Allyson Released a New Single Titled “Ilekun”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.
Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed
Stream and Download Mp3/Music Below:
What Do You Think About This Audio?
We Want To Hear From You All
Kindly Drop Your Comments
Watch Video (Mp4) Below:
Ilekun Lyrics By Sola Allyson
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka o!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Eyin to wa n'ibi imole, tan imole, imole yo!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Eyin to wa n'ibi imole, tan imole, imole yo!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa! (Oba Ogo wo ‘le yi wa aaaaaaaa)
Imole wo ‘le! (Imole wo ‘le eeeeeeeee)
Okunkun ka! (Okunkun kaaaaaaa)
Okun ja! (Okun jaaaaaaaa)
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
Ki lo n ti ilekun? Ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
E gb' ori yin soke, eyin enu ona, ilekun si!
Oba Ogo wo ‘le yi wa, ilekun si!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Eyin to wa n'ibi imole, tan imole, imole yo!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Eyin to wa n'ibi imole, tan imole, imole yo!
Ki lo n fa okunkun? Okunkun ka!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
A ti tu mi sile, mo gba ominira, okun ja!
Ki lo n fa igbekun? Okun ja!
Other Songs From For Sola Allyson Also Can Be Downloaded HERE