Free Download “L'oro L'ero Ati Ni'se” SONG By tope alabi
Nigerian Christian/Gospel Artiste Tope Alabi Released a New Single Titled “L'oro L'ero Ati Ni'se”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit.
Available Now at all Major Digital Music Streaming providers & Gospelmetrics. Kindly Share & Stay being blessed
Stream and Download Mp3/Music Below:
What do you think about this Audio?
We want to hear from you all
Drop your comments
Watch Video Mp4 Below:
L'oro L'ero Ati Ni'se (Lyrics) – Tope Alabi
Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a'tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise
Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo'tun re
Iranwo re yo mumi d'ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise
Verse 3
Emi o mayo s'oluwa, oba ati ase mi
Fi'bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at'ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise
Other Tracks From Tope Alabi Also Can Be Downloaded HERE