Home Gospel Music Sola Allyson – Obirin

Sola Allyson – Obirin

Download “Obirin” SONG By

Sola Allyson - Obirin

Nigerian Christian/Gospel Artiste Released a New Single Titled “Obirin”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What Do You Think About This Audio?

We Want To Hear From You All

Kindly Drop Your Comments

Watch Video (Mp4) Below:

Obirin Lyrics By Sola Allyson
Obinrin ni mi, mo pe lola
Obinrin ni mi, ma rin ma soge
Marin gere bi eni egbe ndun, ma tun sapa genge
Emi ni oluranwo oko emi
Emi l'angeli omo, eledumare lo mo mi
Emi ni iya kowa, eke mi
Mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe
Ko si asise niseda mi
E bami yo
Eni tomo mi eledami ajike o se
Eledua mo gbosuba, moyika otun mo yitosi tori o da mi labo
Omo ero ni mo ba wa itura ni mo je fun aye
Latori mi de ekan ese adesewa gan ni mi
Angeli ori ile lo mi se mo dupe
Iya iya ijoye emi na ni olutoju
Adn aye ni mo je oo
Ebami yoo
Obinrin ni mi, mo pe lola
Obinrin ni mi, ma rin ma soge
Marin gere bi eni egbe ndun, ma tun sapa genge
Emi ni oluranwo oko emi
Emi l'angeli omo, eledumare lo mo mi
Emi ni iya kowa, eke mi
Mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe
Ko si asise niseda mi
E bami yo
Mo yaato gedegbe emi gangan lemi oo
Iseda mi yaato mi o ni fi elomi se ra mi
Mo ni ewa atorun, mori mori
Ola mi o la kawe emi wura iyebiye
Emi ni emi segi, emi ni emi
Owo o le ra mi oo,
Owo o le ra ifemi
Owo o le ra mi oo
Ema sope temi bawo
Ike lo to si mi
Emi ladun aye yi o
E ba mi yoo
Obinrin ni mi, mo pe lola
Obinrin ni mi, ma rin ma soge
Marin gere bi eni egbe ndun, ma tun sapa genge
Emi ni oluranwo oko emi
Emi l'angeli omo, eledumare lo mo mi
Emi ni iya kowa, eke mi
Mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe
Ko si asise niseda mi
E bami yo
Instrument
Laisi emi ibisi iresi o si oo
Mo mu ase wa ni pa ibisi ati iresi
Apo inumi ni omo gbe oo
Inu mi logbomo
Mo deje lomo lori oo
Omu aya mi lo mu
Eyin mi ni orun ti n dun
Olu to re ni mi
Olubi oluto, oloja oluto
Olobe olofa
Aje sanra aje dagba
Bi iya kuro leyin omo iya nla gbmo san le
Mi o ki se atemere
Emi o ki se atemere
Emi obinrin
Obinrin ni mi, mo pe lola
Obinrin ni mi, ma rin ma soge
Marin gere bi eni egbe ndun, ma tun sapa genge
Emi ni oluranwo oko emi
Emi l'angeli omo, eledumare lo mo mi
Emi ni iya kowa, eke mi
Mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe
Ko si asise niseda mi
E bami yo
Obinrin ti o gve gele sile ti o lo wa fala mori ise onise lo je
Ibi aran ni si la gbe, ka le layo ti poo o
E ba je ki atoju aye lara oko lara omo
Ifankan vale ojo ale gan gan lo se koko
E je ki a mura bi o se to
Ki buba wa bo ododo
A ki se atemere X 2
Awa ki se atemere
Awa obinrin
Obinrin ni mi, mo pe lola
Olami pe mo ni ewa atorun
Obinrin ni mi, ma rin ma soge
Marin gere bi eleni gere, ma tun sapa genge
Emi ni oluranwo oko emi ni
Laisi emi ko si omo
Emi ni eni angeli omo eledumare lo mo mi
Emi ni iya ti o wa eke mi
Mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe
Ko si asise ninu eda mi
E bami yo.

Other Songs From For Sola Allyson Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here