Gospelmetrics Forum

Chissom Anthony - The Comeback King  
Home Gospel Music Sola Allyson – Olorun Awon Omo Ogun Master

Sola Allyson – Olorun Awon Omo Ogun Master

Download “Olorun Awon Omo Ogun Master” SONG By

Sola Allyson - Olorun Awon Omo Ogun Master

Nigerian Christian/Gospel Artiste Released a New Single Titled “Olorun Awon Omo Ogun Master”, Which is a Powerful Song That Will Uplift Your Spirit And Surely Be Worth A Place On Your Playlist.

Available Now on Gospelmetrics For Free Download, Kindly Share & Stay being blessed

Stream and Download Mp3/Music Below:

DOWNLOAD HERE

What Do You Think About This Audio?

We Want To Hear From You All

Kindly Drop Your Comments

Watch Video (Mp4) Below:

Olorun Awon Omo Ogun Master Lyrics By
Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọba tó f’amo mo wá
Ọba tó lẹ’ mi wá
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
Ọba t’ó f’amo mo wá
Ọba t’ó lẹ’ mi wá o
Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún
Níbi tó lẹ’wá julo ni Ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o
Imọ’lẹ’ láṣọ re
Ọlá lo fi ṣá’so bora
Níbi tó lẹ’ wá julo ni ìwọ gbé
Lórí obiiri ayé ni’wo wá o
Imọ’lẹ’ láṣọ rẹ
O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora
Mo padà wá bí orísun ìfẹ’ àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ’ mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Mo padà wá bí orísun ìfẹ’ akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o
Ọba tó lẹ’ mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Ahhhhh Ahhhhh
Ìwọ lọ lèmi mi ò
Ìwọ lo nígbà mi
Ìṣẹ’lẹ’ inú ìṣẹ̀dá nṣá’fihàn àgbàrá rẹ
Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o
Pẹ’lú ifilelẹ’ tí ó lè Páráda láì láì
Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́n
Ṣe bí èyí tà ri là ń wi
Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye
Àìmọye làwọn tá kan n mo l’àrà
Ẹ’dá ó lè ṣá kàwé wọn
Ibí tó lẹ’wá julo ni ìwọ gbé
órí obiiri ayé ni’wo wá o
Imọ’lẹ’ láṣọ rẹ
O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora
Mo padà wá bí orísun ìfẹ’ àkókò
Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi
Ọba tó lẹ’ mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Mo padà wá bí orísun ìfẹ’ akoko
Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh
Ọba tó lẹ’mi mi
Ọba tó ní gbà mi
Ògo ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ògo Ìyìn ọlá
Lóye Ọlọ́run
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun
Call: Àìmọye àwọn èyí tá’ ó lé mọ’ bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ
Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún
Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ’n bá ti ọgbọ’n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún
Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún
Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ
Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogún
Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ’ á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì
Resp: Ọlọ’run àwọn ọmọ ogun
Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní
Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Related Post:  Sola Allyson - Ayò Dé !

Other Songs From For Also Can Be Downloaded HERE

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here